Fatima Akilu
Fatima Akilu jẹ́ onímọ̀ ìmọ̀ èrò ọ̀kan, onkọ̀wé, ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tó jẹ́ Mùsùlùmí, O jẹ́ aláṣẹ ìjọba àtijọ́,alagbawi ẹ̀kọ́ ati agbọrọsọ ilu lórí àwọn ọ̀rọ̀ tó n ṣe ìdènà àti ìdènà ìwà ipá ilé àti òpópónà (countering violent extremism (CVE) ) àti ìdènà iwa apanilaya (Countering terrorism).
Fatima Akilu | |
---|---|
United States Institute of Peace 2023 | |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹ̀kọ́ | Beechwood Sacred Heart School |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Mount St. Mary's University (Los Angeles)(BA) University of Reading (MRes and PhD) |
Iṣẹ́ | Psychologist Countering Violent Extremism Expert Executive Director of the Neem Foundation Author Educator |
Notable work | Counselled John Hinckley Jr, Pioneered Nigeria's CVE Programme |
Ní ọdún 2023, ó jẹ́ olùdarí ilé iṣẹ́ Neem Foundation, àti olùdarí ṣáájú ní Behavioural analysis and strategic communication tí ọfíìsì Olùgbéga Ààbò Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, níbi tí ó ti sa agbára láti dá ètò àkọ́kọ́ tí orilẹ̀-èdè yìí tó n ṣe ìdènà ìwà ipá ilé àti òpópónà (countering violent extremism). Akilu jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ ilé iṣẹ́ Global Strategy Network pẹ̀lú amòfin tó ni ìmòye Richard Barrett.
Akilu kọ àwọn ìwé ẹ̀kọ́ fún àwọn ọmọ kékeré àti alabaṣepọ ẹgbẹ́ Women’s Alliance for Security Leadership (WASL). Òun ni Atọkun ètò rádíò àtijọ́ Radio Psych, ètò tó dojú kọ́ àwọn ọ̀rọ̀ ilé àti ọ̀rọ̀ èrò ọ̀kan.[1][2][3][4]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Archived copy" (PDF). Archived from the original (PDF) on 2017-05-21. Retrieved 2017-01-30. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Dr. Fatima Akilu | neem". Neemfoundation.org.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2017-02-01.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "WHO WE ARE". Theglobalstrategynetwork.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2017-10-31. Retrieved 2017-02-01. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs nameddcaf