Fatma Ali
Fatma Othman Ali (tí a bí ní ọjọ́ kejìdínlógbọ̀n oṣù kẹsàn-án ọdún 1950) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ ède Tanzania tí ó fi ìgbà kan jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ ilé ìgbìmọ̀ asofin Tanzanian kẹsàn-án. Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú Chama Cha Mapinduzi.[1]
Fatma Ali | |
---|---|
Member of the Tanzanian Parliament | |
In office 2005–2010 | |
Constituency | Special Seat |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 28 Oṣù Kẹ̀sán 1950 |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Tanzanian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | CCM |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Member of the Tanzanian Parliament". Parliament of Tanzania. Archived from the original on 26 January 2014. Retrieved 19 May 2013. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)