Fatuma Issa Maonyo
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Fatuma Issa Maonyo | ||
Ọjọ́ ìbí | ọjọ́ kẹ̀sán osù Kẹrin ọdún 1995 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Tanzania | ||
Playing position | Olùgbèjà | ||
Club information | |||
Current club | Simba Queens | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Simba Queens | |||
National team | |||
Tanzania | |||
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 2 March 2022. † Appearances (Goals). |
Fatuma Issa Maonyo tí a bí ní ọjọ́ kẹ̀sán osù Kẹrin ọdún 1995 jẹ́ ogbóǹtarìgì agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀-ède Tanzania tí ó ṣeré ipò olùgbèjà lórí pápá fún Simba Queens àti ẹgbẹ́ <a href="./Boolu-afesegba" rel="mw:WikiLink">agbábọ́ọ̀lù</a> obìnrin Tanzania .
Isẹ́ Òkè-òkun
àtúnṣeNí Oṣù Keje ọdún 2018, Maonyo borí ní bi ìdíje CECAFA Women's Championship ti ọdún 2018 pẹ̀lú Tanzania lẹ́hìn tí ó ṣẹ́gun Etiopia pẹ̀lú àmì ayò mẹ́rin si ọ̀kan (4-1) ní bi ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ ìkẹhìn wọn.
Àwọn ọlá
àtúnṣe- Asiwaju Awọn Obirin CECAFA : 2018
- Oṣere asiwaju Awọn Obirin ti CECAFA ti Idije : 2018