Federal university of Lokoja
University ni Kogi State
Fulokoja tàbí ti àpè ní kúkurú jẹ́ FUL, ó jẹ́ ilẹ́ ẹ̀kọ́ fásitì ti ìjọba àpapọ̀ tí ó wà ní ìlú Lokoja, ní ìpínlẹ̀ Kogi State, tó wà ní àárín gbùngbùn Àríwá orílẹ̀ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ( Nigeria.) Lokoja wà ní abẹ́ odò Niger àti Benue.
Federal University Lokoja | |
---|---|
Motto | Sic Itur Ad Astra |
Motto in English | The sky is the limit |
Established | 2011 |
Type | Public |
Vice-Chancellor | Olayemi Akinwunmi |
Academic staff | 5 |
Location | Lokoja, Nigeria |
Campus | Urban |
Colors | Navy blue and Sky Blue |
Website | fulokoja.edu.ng |
A dá Ilé ẹ̀kọ́ fásitì ìjọba àpapọ̀ Lokoja sílẹ̀ ní oṣù kejì ọdún 2011, ìjọba àpapọ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà dá ilẹ́ ẹ̀kọ́ gíga yìí sílẹ̀ látarì ṣíṣẹ̀dá àwọn ilẹ́ ẹ̀kọ́ gíga (universities) sí ní orílẹ̀ èdè.[1][2][3]
Àwọn Ẹ̀ka Ẹ̀kọ́
àtúnṣeTún wo
àtúnṣeExternal links
àtúnṣeÀwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Federal University, Lokoja - Educationgist.com". Archived from the original on 2020-02-02. Retrieved 2024-02-21.
- ↑ Tosin Makinde (7 October 2021). "Defence Academy students seek partnership with varsity".
- ↑ Coker Hope Afe (Physics, Fulokoja). "5 new faculties In Federal University Lokoja". Archived from the original on 2020-02-02. Retrieved 2024-02-21.
- ↑ https://www.fulokoja.edu.ng/
- ↑ ".:: Prof. Akinwumi Redoubles Efforts to Building Greater FUL, Reiterates Unwavering Commitment to his Vision Plan | Federal University Lokoja".