Fẹlá Kútì
Fẹlá Aníkúlápo Kútì (orúkọ ìbí Olúfẹla Olúṣ́ẹgun Olúdọ̀tun Ransome-Kútì, October 15, 1938 - August 2, 1997) tàbí Fẹlá jẹ́ olórin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Fẹlá Aníkúlápo Kútì (orúkọ ìbí Olúfẹla Olúṣ́ẹgun Olúdọ̀tun Ransome-Kútì, October 15, 1938 - August 2, 1997) tàbí Fẹlá jẹ́ olórin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ọ̀tùń jẹ́ ádììjá gbárá fun awọ̀ń ọ̀mọ̀ orílẹ́- èdé Nàìjíríà ose tun ma kọ̀ orin . Wọ̀ń mọ̀ ṣí ẹ́ńì tì òsìwájù orin awọ̀ń áláwọ̀ dúdù.
Fẹlá Kútì | |
---|---|
![]() | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Olúfẹlá Olúṣẹ́gun Olúdọ̀tun Ransome-Kútì |
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | Fela Anikulapo Kuti Fela Ransome-Kuti |
Ọjọ́ìbí | Ábẹ́òkúta Nigeria | 15 Oṣù Kẹ̀wá 1938
Aláìsí | 2 August 1997 | (ọmọ ọdún 58)
Irú orin | Afrobeat, Highlife |
Occupation(s) | Singer-songwriter, instrumentalist, activist |
Instruments | Saxophone, vocals, keyboards, trumpet, guitar, drums |
Years active | 1958–1997 |
Labels | Barclay/PolyGram, MCA/Universal, Celluloid, EMI Nigeria, JVC, Wrasse, Shanachie, Knitting Factory |
Associated acts | Africa '70, Egypt '80, Koola Lobitos, Nigeria '70, Hugh Masekela, Ginger Baker, Tony Allen, Fẹ́mi Kútì, Ṣeun Kútì, Roy Ayers, Lester Bowie |
Website | felaproject.net |
Fẹ́lá Kùtì jẹ́ ọ́mọ̀ àdìjà gbárá fùń ẹ́tọ̀ àwọ̀ń óbìnrìń , Iya áfìń Funmilayo Ransome Kuti. Ni ígba tì odé lá tì ìlù oyinbo , orin ẹ́ kan ti óńjẹ́ Africa '70, Ni ọ̀dùń 1970. Nì ọ̀dùń yì ńì áwọ̀ń ìjọ̀bá Áláàgbádá lòwá lòrì ípò tì o sì fìń orìń ẹ́ fì bawọ̀ń wì.[3] Ni ọ̀dùń yi náà nì ò dá ," Kalakuta Republic commune", Ti o si yọ̀ ara ẹ́ kurọ̀ nìnù ijọ̀bá álágbádá. Ìjọ̀ communì yi pada dara ni ọ̀dùń 1977. Lati igba ti fela kuti ti di ólògbè Ni ómò rẹ́ Femì Kutì tì kò gbógbò òrìń ẹ́ sì òjù káń.
Ìbẹ́rẹ̀ ayé rẹ̀Àtúnṣe
Olufela Olusegun Oludotun Ransome-Kuti wọ̀ń bì nì ọ̀dùń 1938, october 15, sí ìlù Abẹ́okùtà ńììpìńlẹ́ Ogun,Ni orí lẹ́dẹ́ Ńáìjìríá. Gẹ́gẹ́ ì áṣè mọ̀ pẹ́adìja gbárá fùń ẹ́tọ̀ áwọ̀ń obìń rìń ńì íyá rẹ́,Chief Funmilayo Ransome -Kuti ,tì bábá rẹ́ ṣì jẹ́ Rẹ́vẹ́ńdí tì ìjọ̀ Ańglícáń ,òlùkọ̀ ágbá átì Àrẹ́ fùń gbògbó Olùkò. Awọ̀ ọ̀mọ̀ Iya rẹ́ ńì Beko Ransome-Kuti átì Olikoye Ransome-Kuti, Dọ̀kìtá Ti wọ̀ń mọ̀ ka kiri. Fẹ́lá tùń tọ̀mọ̀ Ọ̀Jọ̀gbọ̀ń Wolẹ́ Sòyìńká ẹ́ni ti ojẹ́ alakọ̀ ńi álàwọ̀ dùdù tì ògbá ebùń lìtírátùrẹ́.
Kuti lọ̀sì Ile iwe girama schol Ti Ilu Abẹ́okùtá .Ni ọ̀dùń 1958,o lọ̀ si okè okùn lọ̀ká medìcìń ṣùgbọ̀ń òpá dá lọ́ sì ìle íwé káń tì wòń pè nì Trinity College of Music, iyẹ́ń Ile iwe orin. Kákákì ni ofẹ́ rán latì má fi kọ̀ orìń. Ni Igba ti iwa ni ọ̀ hun odá ẹ́gbẹ́ orin titi ẹ́ Ti osi jẹ́ Koola Lobitos,Ti wọ̀ń kọ̀ jazz Ati highlife Ni ọ̀dùń 1960,Fela fẹ́ iyawo rẹ́ Ti oke Re mi le ku un Kuti Ti ó si bi ọ̀mọ̀ meta fun ti orunọ̀ wan sìjẹ̀ (Femi,Yemi ati Solá). Ńì òdùń 1963, Kuti pádá sì Náìjìríá lẹ́yìń ìgbá tì otì gbá òmìnìrá ,osì yì egbẹ́ orìń ẹ́ ,.
Ni ọ̀dùń 1967, Kuti lọ̀sì Ori lẹ́dè Gháńá lati lọ̀wá awọ̀ń ọ̀ńọ̀ òríń ìmì. Ona pe orin titi ẹ́ Ni Afrobeat, iyẹ́ń ti ṣe ápápọ̀ highlife,fun,jááz ,sálsá, cálypsò Ati ọ̀rìń ìjìńlẹ́ ílẹ̀ yòrùbá .
Bì Fẹ́lá ṣẹ́ ja fùń ẹ́tọ̀ árá ìlùÀtúnṣe
Bí Fela ṣì ṣẹ ijàgbárá ńà, bẹ́ńì wọ̀ń fì pàmọ̀ sì ágọ̀ ọ̀lòpá. Ńì gbọ̀gbọ̀ ígbá tì òbá fì ìfè ińù àháń ńì wọ̀ń má mù lọ̀ sì ìlè ìpámọ̀, bẹ́ ńàńí wọ̀ń mà lọ̀ fì íyá jẹ́ áwọ̀ń íyáwò átì áwọ̀ń ọ̀mọ̀ rẹ́. Felá Kuti jẹ̀ ádìjáá gbárá fùń étọ̀ ará ìlù tìtì ófì dì ològbé. Kuti má dojù kọ̀ áwọ̀ń ìjọ̀bá Náijìrìa fùń gbògbó ìwá ibájé tì wọ̀ń wù sí awọ̀n árá ìlù tí wọ̀ń fí wọ̀ń sí ìpò. Fela jé kí wọ̀ń mọ̀pé àwọ̀ oyìńbò ńì wọ̀ń dá wá lá sí ìlù naìjírìá. Fela tun je ki wọ̀ń mò awọ̀ń iwa ibaje kan ti owa laarin awọ̀ń aláwọ̀ dudu bi ki á má gba abẹ́tẹ́lẹ̀,ki á má ṣè otọ̀, ọ̀jùkòkórọ̀ , kì wọ̀ń má dà ibò rù , kì wọ̀ń má gbẹ́ nì pá, jagidijagan áti bẹ́bẹ̀ lọ̀
Ìpá tí ò fì lẹ́Àtúnṣe
Gbogbò ẹ́ńiyáń ńì wọ̀ń mọ̀pè Fela Kuti jẹ́ ákìńkọ̀jù tí ọ́fì orin ẹ́ má tùń ìlù ṣé. Áyẹ́yẹ́ káń tí wọ̀ń pè nì " Felabration " tì wọ̀ń ṣè nì ọ̀dọ̀dùń látì fí ṣè iráńtì ólògbè Fela Kuti gègé bì eńí tì órìń rè wùyì láwùjọ̀.
Ńí ọ̀dùń 1999, Universal Music France, ńì ábè Francis Kertekian, gbẹ́ álbùmù ọ̀gọ̀jì òlè márùń jádé bẹ́ ńì wòń tí gbá áyé ńì òkè-òkùń.
Òlòrìń káń tí wòń pè ńì Bìlál látì órì lẹ́dẹ́ Amẹ́rícá tùń òrìń Fela ṣé ńì Ọ̀dùń" 1997 ti akọ̀lé re si jẹ́ "Sorrow Tears and Blood".Àtúnṣe
Ńì ọ̀dùń 2007 ńí ẹ́ré órì tágé káń tì ákọ̀lé rè sì jè "The Visitor"(Áléjò) tì árá kùń rì káń tò jé Thomas McCarthy tò dáàrì . Éréyì ṣé áfíháń òjògbòń káń tì ońjẹ́ (Richard Jekins) Ti ó fe gbọ̀ orin kan ti akọ̀lé re jẹ́ "djembe" Ti o kọ̀ lati ọ̀dọ̀ ara kùńrí kan ti á pe ni Haaz Sleiman tì òwá látì òrìlẹ́dẹ́ Syria , Haaz Sleiman ṣì sọ̀fùń ọ̀jọ̀gbọ̀ń yì pẹ́ , kòsì bì òhùń yì ò lé gbò ágbọ̀yè òrìń áwòń álàwò dùdù áyàfì tí òhùń bàtò gbò órìń Fẹ́lá. Ńìńù èré yì ńáńì wòń tì ṣè áfìháń órìń Fela Mèji káń tì ákọ̀lè wòń sìjẹ́ "Open and Close " átì " Jẹ́ ń wì tèmì".
Ni Igba aye rẹ̀ ó ri si ri ṣì ikan lòfìlélẹ̀, bẹ́ńá Ni wọ̀ń fun ni orìṣì ri si ẹ́bùń to pọ̀ jáńtìrẹ́rẹ́. Wọ̀ń si tun fi ka le ni ẹ́mẹ̀ ọ̀káńlà latì fì gbá ẹ̀bùń
Àwọn àṣàyàn orin tí ó kọ sílẹ̀Àtúnṣe
Fela Fela Fela jade ni ọ̀dùń 1969, Live! (1971)
Rọ̀fọ̀rọ̀fọ̀ jadé ńì ọ̀dùń 1972
Shakara ni ọ̀dùń1973
Open & Close (1971),Ni odùń 1972 oṣé akolè orin kan ti on je "Shakara" , A
Rọ̀fjade ni ọ̀dùń ọ̀jade ńì rọ̀fọ̀ Fjade ni ọ̀dùńight (1972)
Afròdisiác (1973)
Gentleman (1973)
Confusion (1975)
Expensive Shit jádé ni ọ̀dùń (1975)
He Miss Road jádé ni ọ̀dùń(1975)
Water No Get Enemy jádé ni ọ̀dùń(1975)
J.J.D. (Johnny Just Drop!!) (1977) Fela Kuti
Zombie jádé ni ọ̀dùń (1977)
Stalemate naa jádé ni ọ̀dùń (1977)
No Agreement jádé ni ọ̀dùń (1977)
Sorrow Tears and Blood. jádé ni ọ̀dùń (1977)
Shuffering and Shmiling jádé ni ọ̀dùń (1978)
Black President jádé ni ọ̀dùń (1981)
Original Sufferhead jádé ni ọ̀dùń (1981)
Unknown Soldier jádé ni ọ̀dùń (1981)
Army Arrangement.jádé ni ọ̀dùń (1985)
Beasts of No Nation.jádé ni ọ̀dùń (1989)
Confusion Break Bonesjádé ni ọ̀dùń (1990) áti bébé lọ̀