Fẹ́mi Adébáyọ̀
Òṣéré orí ìtàgé
(Àtúnjúwe láti Femi Adebayo)
Fẹ́mi Adébáyọ̀ (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kọkànlélọ̀gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 1973) [1] jẹ́ amòfin, gbajúmọ̀ òṣèré, olóòtú àti olùdarí sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí Ìlọrin ni ìpínlẹ̀ Kwara. Bákan náà Fẹ́mi Adébáyọ̀, títí di ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù karùn-ún ọdún 2019 jẹ́ Olùdámọ̀ràn Pàtàki lórí àṣà, ìrìn-afẹ́ àti iṣẹ́-ọ̀nà fún Gómìnà ìpínlẹ̀ Kwara àná, Abdulfatai Ahmed. Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ gbajúgbajà òṣèré sinimá àgbéléwò, Adébáyọ̀ Sàlámì, tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Ọ̀gá Bello.
Fẹ́mi Adébáyọ̀ | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Lagos, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian (1978-present) |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1985-present (Ogun Ajaye) |
Parent(s) | Adebayo Salami |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Femi Adebayo, Actor, Producer, Nigeria Personality Profiles". Nigeria. Retrieved 2019-12-13.