Dafidi Oluwafemi (itumo: "eni ti Olúwa feran") Adewunmi Abdulateef Fani-Kayode je oloselu ni orile-ede Naijiria, onkowe, a fi-oro-dara ati agbejoro. O je omo Egbe oselu ti o nse ijoba (PDP). O fi igba kan dara po mo egbe alatako APC ki o to pada si Egbe PDP ni osu kefa odun 2014 . Bi o tile je pe awon ebi re wa lati Osun, ilu Eko ni a ti bi, ni ojo kerin-din-logun osu kewa odun 1960 fun Oloye Victor Babaremilekun Adetokunboh Fani-Kayode ati Oloye (Iyaafin) Adia Adunni Fani-Kayode. Oloye ni ni Ile-Ife o wa lati iran Yoruba.

Femi Fani-Kayode
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Femi Fani-Kayode

16 Oṣù Kẹ̀wá 1960 (1960-10-16) (ọmọ ọdún 63)
Lagos, Lagos State, Nigeria
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
ProfessionLawyer

Fani-Kayọde ni oludamoran pataki (lori oro nipa ara ilu) fun Áárẹ Oluṣẹgun Ọbasanjọ lati osu kejo odun 2003 titi di osu kefa odun 2006. A yan gegebi alamojuto oro to je mo Asa ati Igbafe ni orile-ede Naijiria lati ojo keji-le-logun osu kefa si ojo keje osu kokanla odun 2006 ati gegebi alamoju fun oro to je mo irina oju ofurufu lati ojo keje osu kokanla odun 2006 titi di ojo kokan-din-logbon osu karun odun 2007.[1][2][3][4][5][6][7][8]

Ìbẹ̀rè Ìgbé Ayé àti Ẹ̀kọ́ àtúnṣe

Bàbá tó bí bàbá bàbá rẹ̀, Àlúfà Èmánúẹ́lì Adédápọ̀ Káyọ̀dé, jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàíjíríà tí ó kọ́kọ́ lọ kà'wé ní Ìlú Ọba gb'oyè akọ́'ṣẹ́ mọ'ṣẹ́ láti ilé ẹ̀kọ yunifásitì ti Durham, leyin eyi ti o di alufa ni ijo Angilikan after which he became an Anglican priest. His grandfather, Victor Adedapo Kayode, studied law at Cambridge University and became a lawyer and a judge. His father Victor Babaremilekun Adetokunboh Fani-Kayode, who was also at Cambridge was a prominent lawyer and political figure in Nigeria in the 1950s and 1960s. He was Leader of the National Council of Nigeria and the Cameroons Opposition in the Western House of Assembly from 1960 to 1963, the Hon. Minister of Local Government and Chieftaincy Affairs and Deputy Premier of the Western Region of Nigeria from 1963 until 1966 and he successfully moved the motion for Nigeria's independence in 1958 in the Nigerian Parliament.[9][10]

References àtúnṣe