Femi Hamzat
Olóṣèlú
Dokita Kadri Obafemi Hamzat (ti a mọ ni Femi Hamzat) jẹ Igbakeji Gomina Ipinle Eko fun Gomina Babajide Olusola Sanwo-Olu. Won dibo yan Obafemi Hamzat pelu Gomina Sanwo-Olu ni odun 2019 labe asia egbe-oselu All Progressives Congress (APC). Obafemi Hamzat ti fi Igba kan je Komisona fun eto-ise no ipinle Eko ni akoko isejoba Gomina-ijeta ni ipinle Eko, Babatunde Raji Fashola, Nàìjíríà . Saaju, A yàn-an gẹgẹbi Komisona fun Ijoba Lori Imọ ati Imọlẹ-ẹrọ, Ipinle Eko ni August 2005. O si ṣe ipo naa titi di osu kefa 2011. Lẹhin naa, o tun yan Komisona fun Awọn iṣẹ ati Awọn Imọ-ara [1] nipasẹ iṣakoso Gomina Babatunde Raji Fashola ni Ọjọ kerin Oṣu Keje 2011.
Dokita Kadri Obafemi Hamzat | |
---|---|
Femi Hamzat ní Hackathon ní Ìpílẹ̀ Èkó ọdún 2020. | |
Commissioner, Ministry of Works and Infrastructure Lagos State | |
In office 2011–2015 | |
Asíwájú | Rauf Aregbesola |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 19 Oṣù Kẹ̀sán 1964 Lagos, Nigeria |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | All Progressives Congress (APC) |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Mrs Oluremi Hamzat |
Alma mater | University of Ibadan |
Occupation | Engineer, Politician |
Profession | Engineering |
Website | http://kohlagos.com.ng/ |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Ipinle Eko ti Oṣiṣẹ ati Amayederun "Dokita Kadri Obafemi Hamzat, Komisona ti Awọn Iṣẹ ati Awọn Imọlẹ-ara" Archived 2013-07-14 at the Wayback Machine. , aaye ayelujara Ipinle Eko