Femi Taylor
Femi Taylor (bíi ni ọjọ́ kẹjọ oṣù kẹrin ọdún 1961) jẹ́ oníjó àti òṣèré ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí ó gbajúmọ̀ fún ipá Oola tí ó kó nínú eré Return of the Jedi ní ọdún 1983.[1] Ó kó ipa Tantomile nínú eré orin tí Cats ni ọdún 1981. Femi jẹ́ ìyàwó fún Clauis Skytte Kamper, ó sì ti bí ọmọ méjì.
Femi Taylor | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 8 Oṣù Kẹrin 1961 |
Iṣẹ́ | Actress, dancer |
Ìgbà iṣẹ́ | 1980–present |
Alábàálòpọ̀ | Claus Skytte Kamper |
Àwọn ọmọ | 2 |
Àṣàyàn àwọn eré tí ó tí ṣe
àtúnṣeỌdún | Àkọ́lé eré | Ipa tí ó kó |
---|---|---|
1980 | The Apple | Dancer |
1983 | Return of the Jedi | Oola |
1987 | Playing Away | Masie |
1990 | A Kink in the Picasso | Nadia |
1991 | Flirting | Letitia Adjewa |
1998 | Cats | Exotica |
Àwọn ìtọ́kàsi
àtúnṣe- ↑ Matt Forbeck (2011). Star Wars vs. Star Trek: Could the Empire kick the Federation's ass? And other galaxy-shaking enigmas. Adams Media. p. 34. ISBN 9781440525773. https://archive.org/details/starwarsvsstartr0000forb. "Femi Taylor actress."