Fesikh

Oúnjẹ ìbílẹ̀ ní Egypt

Fesikh (Àdàkọ:Lang-arz, arz) jẹ́ oúnjẹ ayẹyẹ ìbílẹ̀ Egypt. Ó jẹ́ oúnjẹ jíjẹ àwọn ara Egypt ní àkókò ọdún Sham el-Nessim ní Egypt, èyí tí ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ayẹyẹ Egypt láti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún sẹ́yìn tí wón máa ń ṣe ní àkókò sípíríngì tí ó sì jẹ́ ayẹyẹ gbogbo orílẹ-èdè náà. Fesikh kún fún Àtoko gbígbẹ tí a fi iyọ̀ pamọ́ ti ó jẹ́ ẹjá ẹ̀yà Mugil, oríṣi ẹja òkun tí ó máa ń gbé ní Mediterranean àti Òkun Pupa;[1] ni apá Ìwọ̀-oòrùn Egypt whitefish, gẹ́gẹ́ bíi ìpàrọ̀ rẹ̀.

Fesikh from Desouk.

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Feseekh and Melouha". Baheyeldin Dynasty.