Finding Samuel Lowe: From Harlem to China

Finding Samuel Lowe: From Harlem to China, jẹ́ fíìmù ìtàn-àkọọ́lẹ̀ kan ti ọdún 2015 tí wọ́n ṣe lórílẹ̀-èdè Jamáíkà tí Jeanette Kong ṣe adarí rẹ̀.[1] Fíìmù náà dá lóri òṣìṣẹ́ tẹlifíṣọ̀nù tẹ́lẹ̀ rí tí orúkọ rẹ̀ jẹ́ Paula Williams Madison àti àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀ okùnrin méjì kan tí wọ́n rin ìrìn-àjò láti lọ ṣe ìwádìí nípa bàbá ìyá wọn tí ó fi ìyá wọn sílẹ̀ sí Jamáíkà ní àsìkò àwọn ọdún 1930.[2][3]

Finding Samuel Lowe: From Harlem to China
AdaríJeanette Kong
Olùgbékalẹ̀Jeanette Kong
Òǹkọ̀wéJeanette Kong
Àwọn òṣèréPaula Williams Madison
Elrick Williams
Howard Williams
Ìyàwòrán sinimáMartin Proctor
OlóòtúJane MacRae
Déètì àgbéjáde
  • 25 Oṣù Keje 2014 (2014-07-25)
(Jamaica)
Àkókò88 minutes
Orílẹ̀-èdèJamaica
USA
ÈdèEnglish

Fíìmù náà gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn àmì-ẹ̀yẹ níbi àwọn ayẹyẹ àjọ̀dún fíìmù.[4] Àfihàn àkọ́kọ́ fíìmù náà lórílẹ̀-èdè Jamáíkà wáyé lóri ìkànnì Doc World ní Ọjọ́ 14 Oṣù Kaàrún, Ọdún 2017. Ó síì tún wà lóri ayélujára fún àwon ènìyàn láti wò lọ́fẹ̀ẹ́ láti 15 Oṣù Kaàrún títí di 13 Oṣù Kẹfà Ọdún 2017.[5] Wọ́n wo fíìmù náà níbi ayẹyẹ Pan African Film Festival ní Ọjọ́ Kẹẹ̀jọ Oṣù Kejì, Ọdún 2014.[6]

Àwọn olùkópa

àtúnṣe
  • Paula Williams Madison
  • Elrick Williams
  • Howard Williams
  • Vincent J. Chang
  • Stephen Young Chin
  • Anthony 'Harry' Harrison
  • Ouida Harrison
  • Andrea Lowe
  • Anthony 'Tony' Lowe
  • Chow Woo Lowe
  • Keith Lowe
  • Loraine Lowe
  • Minjun Luo
  • Siqi Luo
  • Seth George Ramocan
  • Carol Wong
  • Dalton Yap

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Finding Samuel Lowe". Finding Samuel Lowe official website. Retrieved 22 October 2020. 
  2. "Finding Samuel Lowe: From Harlem to China: Asia Society Documentary Film Series". Finding Samuel Lowe official website. Retrieved 22 October 2020. 
  3. "DOC WORLD: Finding Samuel Lowe". WGBH Educational Foundation. Retrieved 22 October 2020. 
  4. Wood, Ximón. "Golden Anniversary Visionary Awards Dinner and Silent Auction". East West Players. Archived from the original on 2019-07-22. Retrieved 2019-07-22. 
  5. "Finding Samuel Lowe". CENTER FOR ASIAN AMERICAN MEDIA. Retrieved 22 October 2020. 
  6. "Finding Samuel Lowe". The Africa Channel. Retrieved 22 October 2020. 

Àwọn ìtakùn Ìjásóde

àtúnṣe