Fio Fio

Fio-fio je ounje alata pelu pigeon pea asaro, ounje yi kundun ni Enugun, orile ede Nigeria

Fio Fio jẹ́ ọbẹ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà tó wọ́pọ̀ láàárín apá Gúsù Ìlà-oòrùn, àwọn èròjà gbòógì ọbẹ̀ náà ni irúgbìn gínì àti ìṣù-kòkó.[1]

Ọbẹ fio fio náà jẹ́ ọbẹ̀ ìbílẹ̀ àwọn ará Ìpínlẹ̀ Ẹnúgu.[2]

Lápapọ̀

àtúnṣe

Àwọn èròjà tí wọ́n tún ń lò láti ṣe ọbẹ̀ fio fio ni efinrin, edé, epo pupa àti ùgbá. Wọ́n máa ń se irúgbìn gínì títí tó ma fi rọ̀ papọ̀ mọ́ achicha (ìṣù-kòkó lílọ̀).[3]

àtúnṣe

Àwọn Ìtọ́kasí.

àtúnṣe
  1. Onyeakagbu, Adaobi (2021-05-10). "Fio Fio: How to prepare this spicy traditional Enugu dish". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-28. 
  2. "How To Make Achicha And Fio-Fio". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-08-29. Retrieved 2022-06-28. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  3. "How To Make Achicha And Fio-Fio". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-08-29. Retrieved 2022-06-28. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]