First City Monument Bank

First City Monument Bank (FCMB), ẹgbẹ tí FCMB Group Plc, ó jẹ́ ilé ìṣe tí ìnáwó a dání tí headquartered ní Lagos. FCMB Group Plc ní ẹ̀ka mẹsan tí a pín wọn sì ìṣe owó mẹ́ta: commercial and retail banking, investment banking, and asset and wealth management.[2] Ní Oṣu December 2020,iye tí dúkìá wọ́n ní yé lórí ní US $5 billion (NGN: 2 trillion).[3]

First City Monument Bank Ltd (FCMB)
TypeLimited Company
Founded20 April 1982
Founder(s)Oloye Subomi Balogun
HeadquartersLagos Island, Lagos, Lagos State, Nigeria
Area servedNigeria
United Kingdom
Key peopleOladipupo Jadesimi
Chairman
Ladi Balogun
Group Chief Executive
Yemisi Edun
Managing Director
IndustryFinance
ServicesBanking
RevenueUS $311.1 million (NGN:127.9 billion) (2020)[1]
Total assetsUS $5 billion (NGN:N2 trillion) (2020)
Employees3,610 (2020)
Websitefcmb.com

Ìgbà tí wọ́n kọ́kọ́ dá ilé-ìfowópamọ́ yìí sílẹ̀, orúkọ rẹ̀ ni City Securities Limited (CSL), ọdún 1977 sì ni wọ́n dá a sílẹ̀, láti ọwọ́ Oloye Subomi Balogun, ẹni tó jẹ́ ọ̀túnba Tunwashe ti ìlú Ìjẹ̀bú, tó jẹ́ olórí ìlú Yoruba kan. Ọdún 1982 ni wọ́n dá báǹkì yìí sílẹ̀, pẹ̀lú èso ìdókòwò láti CSL.[4] Wọ́n sọ ọ di ilé-iṣẹ́ aládàáni ní ọjọ́ 20 oṣù April, ọdún 1982, wọ́n sì gba ìwé àṣẹ láti máa siṣẹ́ ní ọjọ́ 11 oṣù August, ọdún1983.[4] Ó jẹ́ báǹkì àkọ́kọ́ tí wọ́n máa dá sílẹ̀ láìsí ìrànlọ́wọ́ ìjọba tàbí láti òkè òkun.[5] Ní ọjọ́ 15 oṣù July, ọdún 2004, wọ́n yi padà kúrò láti ilé-iṣẹ́ aláàdíni sí ilé-iṣẹ́ ìjọba, wọ́n sí fi sábẹ̀ Nigerian Stock Exchange (NSE) ní ọjọ́ 21 oṣù December, ọdún 2004.[6]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. http://www.fcmbgroupplc.com/images/press/FCMB%20Group%20Plc_FY2020%20Annual%20Report%20&%20Accounts.pdf Archived 29 September 2021 at the Wayback Machine. Àdàkọ:Bare URL PDF
  2. "Obaseki, FCMB's COO, retires". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-03-05. Retrieved 2021-09-15. 
  3. "FCMB Group PLC Annual Report and Accounts" (PDF). Archived from the original (PDF) on 29 September 2021. Retrieved 26 April 2023.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. 4.0 4.1 Oshikoya, Temitope W.; Durosinmi-Etti, Kehinde (2019-05-28) (in en). Frontier Capital Markets and Investment Banking: Principles and Practice from Nigeria. Routledge. ISBN 978-0-429-57770-3. https://books.google.com/books?id=0wSdDwAAQBAJ&dq=%22fcmb+capital+markets+limited%22&pg=PA67. 
  5. "OUR HISTORY". First City Monument Bank. Retrieved 4 March 2020.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. "investorrelations.firstcitygroup.com". investorrelations.firstcitygroup.com. Retrieved 24 August 2017.