Flora Ugwunwa (ti a bi ni ojo kerìndínlọ́gbọ̀n ni odun 1984) [1] je omo orile-ede Naijiria ti o kopa ninu F54 -isori . Arabinrin naa ṣoju orilẹede Naijiria ni ọdun 2016 Paralympics Summer ti o waye ni Rio de Janeiro, Brazil ati pe o gba ami ẹyẹ goodu ninu idije javelin throw F54 obinrin . [2] O tun ṣeto igbasilẹ agbaye tuntun ti 20.25m ni iṣẹlẹ yii.

Flora Ugwunwa
Òrọ̀ ẹni
Ọjọ́ìbí26 Oṣù Kẹfà 1984 (1984-06-26) (ọmọ ọdún 40)
Sport
Orílẹ̀-èdèNigeria
Erẹ́ìdárayáPara-athletics
DisabilityParaplegia
Disability classF54
Event(s)

Arabinrin naa ṣoju Naijiria ni Idije 2020 summer paralympics ni Tokyo, Japan lẹyin ti o gba ami-eye fadaka ninu idije javelin throw F54 awọn obinrin ni 2019 World Para Athletics Championships ti o waye ni Dubai, United Arab Emirates. O tun dije ninu awọn obinrin shot put F54 iṣẹlẹ ibi ti o ti pari ipo kefa ni odun na. [1]

References

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 Empty citation (help)  Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; name "women_shot_put_f54_world_para_championships_2019" defined multiple times with different content
  2. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named paralympic_bio