Florence Earle Coates
Florence Van Leer Earle Nicholson Coates (Ọjọ́ kíníin Oṣù keje Ọdún 1850 – Ọjọ́ kẹfà Oṣù kẹrin Ọdún 1927) jẹ́ akéwì ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà.
Florence Earle Coates | |
---|---|
Florence Earle Coates, pre-1916 | |
Ọjọ́ ìbí | Philadelphia, Pennsylvania, U.S. | Oṣù Keje 1, 1850
Ọjọ́ aláìsí | April 6, 1927 Hahnemann Hospital, Philadelphia, Pennsylvania, U.S. | (ọmọ ọdún 76)
Iṣẹ́ | Poet Philanthropist |
Spouse | Edward Hornor Coates |
Signature |
Ìtàn ìgbésí àyé
àtúnṣeThere's a cabin in the mountains, where the fare, dear,
Is frugal as the cheer of Arden blest;
But contentment sweet and fellowship are there, dear,
And Love, that makes the feast he honors—best!
Wọ́n bíi ní Philadelphia, Pennsylvania. Ó jẹ́ ọmọ ọmọ-bìrin gbajúgbajà afòpin sí òwò ẹrú, Thomas Earle, tí ó jẹ́ àkọ́bí lóbìrín fún amòfin ti Philadelphia George H. Earle, Sr. àti arábìrin Frances ("Fanny") Van Leer Earle, Àrabìrin Coates gbajúmọ̀ ní ilù rẹ̀ àti òkè okun fún iṣẹ́ ewì rẹ̀—bi ọgọ́rún mẹ́ta iṣẹ́ rẹ̀ ló ti di àtẹ̀jáde nínú ìwé lítíréṣọ̀ bi Atlantic Monthly, Scribner's Magazine, The Literary Digest, Lippincott's, The Century Magazine, and Harper's. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ewì rẹ̀ ní wọ́n ti sọ di orín, àwọn olùkọ-orin bí arábìrin H. H. A. Beach (Amy Cheney Beach), Clayton Johns, àti Charles Gilbert Spross ló ti sọ àwọn ewi rẹ̀ di orin. Ó kàwé ní New England lábẹ́ ìtọ́sọ́nà afòpin sí òwò ẹrú àti olúkọ́ Theodore Dwight Weld, tí ó sì fẹ́ tẹ̀síwájú nínú ètpò ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní Convent of the Sacred Heart ní Paris (Rue de Varenne),[1] kí ó sì kọ́ ẹ̀kọ́ orin ní Brussels lábẹ́ ìtọ́sọ́nà gbajúmọ̀ olórin ìgbà yẹn.
Àkójọ àwọn iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeÀwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ The Sacré Cœur (Sacred Heart) in Paris, France was a convent school for young girls run by nuns that fell to the French government as a result of the "religious orders" law of 1904 which involved the separation of church and state, and prohibited religious orders from teaching.
- ↑ Historically listed and referenced as a "Collected edition," Robert H. Walker—in his biographical sketch of Mrs.
Àwọn àjápọ̀ látìta
àtúnṣe- Florence Earle Coates informational blog
- "Florence Earle Coates". Find a Grave.