Florence Griffith-Joyner

Florence Delorez Griffith Joyner[1] (December 21, 1959 – September 21, 1998), bakanna bi Flo-Jo, jẹ́ eléré ìdárayá orí pápá ará Amẹ́ríkà. Wọ́n gbàá gẹ́gẹ́ bí "obìnrin tó yára jùlọ títí aye"[2][3][4] nítorí pé àwọn rẹ́kọ́ọ̀dù àgbáyé tó dà ní 1988 fún ìsáré 100 m àti 200 m kò tíì yipadà, kọ́ sí ti sí èni tó lè yípadà. Ó ṣe aláìsí lójijì lójú ọ̀run nítorí wárápá tó gbée ní ọdún 1998 nígbà tó jẹ́ ọmọ-ọdún 38. Yunifásítì Kalifóníà ní Los Angeles (UCLA) ló ti parí ẹ̀kọ́ rẹ̀.

Florence Griffith Joyner
Florence Griffith Joyner2.jpg
Florence Griffith ní ọdún 1988
Òrọ̀ ẹni
Orúkọ kíkúnrẹ́rẹ́Florence Delorez Griffith Joyner
Ọmọorílẹ̀-èdèAmerican
Ọjọ́ìbí(1959-12-21)Oṣù Kejìlá 21, 1959
Los Angeles, California
Ọjọ́aláìsíSeptember 21, 1998(1998-09-21) (ọmọ ọdún 38)
Mission Viejo, California
Height1.69 m (5 ft 7 in)
Weight59 kg (130 lb)
Sport
Orílẹ̀-èdèÀwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan United States
Erẹ́ìdárayáRunning
Event(s)100 meters, 200 meters
Retired1988

Àwọn ìtọ́kasíÀtúnṣe