Florence Iweta
Florence Iweta jẹ agbabọọlu lobinrin tẹlẹ ri ti a bini 29, óṣu March ni ọdun 1983. Arabinrin naa ṣere fun team awọn obinrin naigiria ti national lori bọọlu gẹgẹbi defender[1][2][3].
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 29 Oṣù Kẹta 1983 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Nigeria | ||
Ìga | 1.68m | ||
Playing position | Defender | ||
National team | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
1999–2003 | Nigeria women's national football team | 2 | (0) |
† Appearances (Goals). |
Àṣeyọri
àtúnṣe- Florence jẹ àṣoju fun órilẹ ede naigiria ni olympics to waye ni ọdun 2000. Arabinrin naa tun kopa ninu Cup FIFA agbaye ni ọdun 1999 ati 2003. Elere naa wa lara team to yege ni ere idije awọn obinrin ilẹ afirica ni ọdun 2000, 2002 ati 2004[4].
Itọkasi
àtúnṣe- ↑ https://www.eurosport.com/football/florence-iweta_prs414911/person.shtml
- ↑ https://fbref.com/en/players/b382941b/Florence-Iweta
- ↑ https://ng.soccerway.com/players/florence-iweta/291444/
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2022-05-29. Retrieved 2022-05-29.