Florence Kasumba (tí a bí ní ọjọ́ kẹrindínlógbọ̀n oṣù kẹwàá ọdún 1976) jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀ èdè Uganda àti Jamini. Ọ̀pọ̀ mọ́ fún ipa tí ó kó gẹ́gẹ́ bí enikan tí ó ń jẹ́ ayọ̀ nínú fíìmù àwọn fíìmù ilé isé Marvel Cinematic Universe bi Captain America: Civil War (2016), Black Panther (2018), Avengers: Infinity War (2018), àti Black Panther: Wakanda Forever (2022), ó tún kó ipa ayò nínú fíìmù Disney+ tí àpèlé rẹ̀ jẹ́ The Falcon and the Winter Soldier (2021). Ó gbajúmọ̀ fún ṣíṣe eré nínú àwọn fíìmù Jámánì àti Dutch. Ó tún kó ipa gẹ́gẹ́ bi Senator Acantha nínú Wonder Woman (2017), Shenzi nínú The Lion King (2019), àti Wicked Witch of the East nínú fíìmù NBC tí àpèlé rẹ̀ jẹ́ Emerald City (2017).

Florence Kasumba
Kasumba at The Lion King European premiere in 2019
Ọjọ́ìbí26 Oṣù Kẹ̀wá 1976 (1976-10-26) (ọmọ ọdún 47)
Kampala, Uganda
Orílẹ̀-èdèJamini
Iléẹ̀kọ́ gígaFontys University of Applied Sciences in Tilburg, the Netherlands
Iṣẹ́Òṣerébìnrin
Ìgbà iṣẹ́2001–present
WebsiteÀdàkọ:Official URL

Ìpìlẹ̀ àtúnṣe

Wọ́n bí Florence Kasumba ní ọjọ́ kẹríndínlógún oṣù kẹwàá ọdún 1976 ní Kampala, orílẹ̀ èdè Uganda.[1] Wọ́n tọ dàgbà ní Essen, Germany, níbi tí ó ti lọ ilé ìwé Alákọ́bẹ̀rẹ̀ àti ilé ìwé Sẹ́kọ́ńdírì. Ó padà gba àmì-ẹ̀yẹ ẹ̀kọ́ nínú eré sise, orin kíkọ àti ijó jíjó ní Fontys University of Applied Sciences ti Tilburg, Netherlands. Ó le sọ èdè Kasumba German, English, àti Dutch. Ó ń gbé ní Berlin, orílẹ̀ èdè Germany.

Àwọn Ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. "A glance at Uganda's Kasumba who featured in Captain America: Civil War". KFM. 26 May 2016. Retrieved 5 November 2016.