Floriano Peixoto
Olóṣèlú Ọmọ Orílẹ̀-èdè Brazil
Floriano Peixoto (tí a bí ní Ọjọ́ ọgbọ́n oṣù keje ọdún 1895) tí ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ "Iron Marshal" jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè, àti ọ̀kan Ààrẹ àwọn Ààrẹ-àná orílẹ̀ èdè náà. A bí i ní ìlú Macelo ní ìpínlẹ̀ Alagoas. Ó jẹ́ ológun àti òṣèlú. Òun ni ọmọ orílẹ̀-èdè Brazil àkọ́kọ́ tí ó kúrò nípò Igbá-kejì-Ààrẹ fi di Ààrẹ. [1] [2] [3]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "História". Folha Online (in Èdè Pọtogí). 1970-01-01. Retrieved 2019-11-16.
- ↑ "Floriano Vieira Peixoto". UOL Educação (in Èdè Pọtogí). 2005-10-10. Retrieved 2019-11-16.
- ↑ "Florianismo - Atlas Histórico do Brasil". FGV (in Èdè Pọtogí). Retrieved 2019-11-16.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |