Folúkẹ́ Dárámọ́lá
Folúkẹ́ Dárámọ́lá jẹ́ gbajúgbajà òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù kejì (15th February) ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Bí Folúkẹ́ tí ń fakọyọ nínú sinimá àgbéléwò èdè Yorùbá, bẹ́ẹ̀ náà ló dáńgájíá nínú tí èdè Gẹ̀ẹ́sì. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ní sinimá àgbéléwò tí ó ti kópa tí ó sìn pegedé. [1] [2] [3]
Folúkẹ́ Dárámọ́lá | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | February 15 |
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Iṣẹ́ | Actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 1998-present |
Àwọn ọmọ | 2 |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ [/foluke-daramola-biography-profile-fabwoman/ "Foluke Daramola Biography - Profile"] Check
|url=
value (help). FabWoman | News, Style, Living Content For The Nigerian Woman. 2019-02-28. Retrieved 2019-12-24. - ↑ "5 things you need to know about actress". Pulse Nigeria. 2016-02-15. Retrieved 2019-12-24.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "FOLUKE DARAMOLA-SALAKO: I briefly left acting when it became monotonous - The Nation Newspaper". The Nation Newspaper (in Èdè Latini). 2019-11-10. Retrieved 2019-12-24.