Folashade Sherifat Jaji
Folashade Sherifat Jaji (ti a bi ni ọjọ́ kẹta oṣù kẹta ọdun 1957) jé osise ìjoba ati akowe fun ijoba ìpínlè Eko.[1] O tún jé akowe fún ijoba Eko Lori eka to un ri soro owó fun awon osise ijoba to ti feyinti[2]. O ran ijoba orílè-èdè Nàìjirià lowo láti mu iyipada rere ba owó ti a fi pamo fún ilo awon osise ìjoba.
Folashade Sherifat Jaji | |
---|---|
Akápò ìjọba ìpínlè Èkó | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 30 May 2019 | |
Lagos State Head of Service | |
In office 17 February 2015 – 26 October 2015 | |
Asíwájú | Josephine Oluseyi Williams |
Arọ́pò | Olabowale Ademola |
Permanent Secretary, Lagos State Ministry of Establishments, Training and Pensions | |
Asíwájú | Tunji Bello |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 10 Oṣù Kẹta 1957 Surulere, Lagos State, Nigeria |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Non-partisian |
Aaro Aye ati Eko re
àtúnṣeA bi Sherifat ni March 3, 1957 ni Surulere, ìpínlè Eko, orílè-èdè Naijiria. O lo ilé-ìwé primari ni ilé-ìwé Anglican Girls Primary to wa ni Surulere, Ìpínlè Eko koto dipe o lo si Queen's college ni Yaba, níbi to ti gba iwe eri WAEC ni odun 1974. O GBA àmì-èye Bachelor of Science ni Yinifasoti ìlú Ibadan, ko to dipe o lo sìrún ìlú(agubaniro) ni okan lara awon ile oti ní Naijiria.[3] O tun pada lo si Yunifasiti ìlú Eko fún àmì-èye master of business administration ni odun 1989.
Ise re
àtúnṣeSherifat bèrè isé ijoba ni October 27, 1980 koto dipe o bere si un sise ni ofici Gomina ipinle Eko, o sise ni ofici Gomina fun odun meji(1980-1982), o ya si eka ise ijoba miran koto dipe o tun pada si un sise ni ofici Gomina fún odun meje(1985-1992)[4][5]
Ni March 1, 2011, o di akowe fun ijoba Eko ni eka to un ri si owo osise feyinti. Ni March 30 2019, a yan gegebi akowe gbogbogbo ijoba ipinle Eko
Àwon Ìtókasí
àtúnṣe- ↑ "GOVERNOR BABAJIDE SANWO-OLU MAKES 1ST APPOINTMENT. NAMES MRS. FOLASHADE SHERIFAT JAJI, FORMER HEAD OF SERVICE AS SECRETARY TO THE STATE GOVERNMENT.". Lagos State Government. 2019-05-30. Archived from the original on 2019-05-31. Retrieved 2022-05-30.
- ↑ "Expert warns retirees on extravagancy". Newswatch Times. 2015-04-06. Archived from the original on 2016-07-03. Retrieved 2022-05-30. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2022-10-24. Retrieved 2022-05-30.
- ↑ "Sherifat Folashade Jaji Becomes Lagos Head of Service". Starconnect Media. 2015-02-20. Retrieved 2022-05-30.
- ↑ Times, Premium (2015-02-18). "Fashola swears in new Head of Service". Premium Times Nigeria. Retrieved 2022-05-30.