Fountain University
Yunifásiti aládàání ní ilẹ̀ Nàìjíríà
Fountain University (FUO) jẹ́ fásitì aládàání ní Osogbo, ní ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣụn, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí á ṣe ìdásílè rẹ̀ láti pèsè ẹ̀kọ́ ní ìbámu pẹ̀lú ìlànà ẹ̀sìn Islam.[1][2] Univesity of Nasrul-lahi-li Fatih ni orúkọ iléẹ̀kọ́ gíga yìí ń jẹ́ tẹ́lè, láti ọwọ́ ìjọ Nasrul-lahi-li Fatih (NASFAT) ní ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù Karùn-ún, ọdún 2007.[3] Ilé-èkọ́ gíga náà ní àwọn ẹ̀ká ẹ̀kọ́ márùn-ún sínú, tí ń ṣe: College of Basic Medical and Health Sciences, College of Natural and Applied Sciences, College of Management and Social Sciences, College of Law, àti College of Arts.
Fountain University, Osogbo | |
---|---|
Fáìlì:Fuo-pt-list-of-courses.jpg Senate Building, Fountain University, Osogbo | |
Motto | Knowledge, Faith and Leadership |
Established | 2007 |
Type | Private |
Religious affiliation | Nasrul-Lahi-L-Fatih Society (NASFAT) |
Chancellor | Alh. Umaru Mutallab CON |
Vice-Chancellor | Professor Olayinka Ramota Karim |
Academic staff | 178 |
Students | 2147 |
Location | Osogbo, Osun, Nigeria |
Colours | Green and Mint |
Website | Official website |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Fountain University". www.4icu.org. Retrieved 9 August 2015.
- ↑ "Nigeria's 59 private universities …locations, Vice Chancellors names, websites, dates of establishment". Kukogho Iruesiri Samson. pulse.ng. 22 April 2015. Retrieved 10 August 2015.
- ↑ Anaekwe, Ikechukwu (August 27, 2023). "Fountain University, Osogbo, Osun State". six33four. https://six33four.ng/blog/article/fountain-university-osogbo-osun-state.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]