François Fillon
François Charles Amand Fillon (ìpè Faransé: [fʁɑ̃swa fijɔ̃]; ojoibi 4 March 1954 ni Le Mans, Sarthe) ni lowolowo Alakoso Agba ile Fransi. O je yiyansipo latowo Aare Nicolas Sarkozy ni ojo 17 May 2007.[1][2] O koko kosesile bi alakoso agba ni 13 November 2010 ki kabineti o to je tuntunda.[3][4]
François Fillon | |
---|---|
Prime Minister of France | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 17 May 2007 | |
Ààrẹ | Nicolas Sarkozy |
Asíwájú | Dominique de Villepin |
Minister of National Education | |
In office 31 March 2004 – 2 June 2005 | |
Alákóso Àgbà | Jean-Pierre Raffarin Dominique de Villepin |
Asíwájú | Luc Ferry |
Arọ́pò | Gilles de Robien |
Minister of Social Affairs | |
In office 7 May 2002 – 31 March 2004 | |
Alákóso Àgbà | Jean-Pierre Raffarin |
Asíwájú | Élisabeth Guigou |
Arọ́pò | Jean-Louis Borloo |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 4 Oṣù Kẹta 1954 Le Mans, France |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Union for a Popular Movement |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Penelope Clarke |
Residence | Hôtel Matignon |
Alma mater | Paris Descartes University |
Profession | Lawyer |
Signature |
Ni ojo 14 November 2010, Aare Nicolas Sarkozy tunyansipo pada bi alakoso agba.[5].
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ "Communiqué de la Présidence de la République concernant la nomination du Premier ministre" (in French). Élysée Palace. 2007-05-17. Retrieved 2007-05-17.
- ↑ "Décret du 17 mai 2007 portant nomination du Premier ministre" (in (Faransé)). Legifrance.gouv.fr. Retrieved 2010-08-04.
- ↑ French Prime Minister resigns before cabinet shuffle - The Globe and Mail
- ↑ "Ko si akole!!!". Archived from the original on 2010-11-15. Retrieved 2010-12-19.
- ↑ "Sarkozy reappoints French prime minister amid cabinet reshuffle". Archived from the original on 2010-11-17. Retrieved 2010-12-19.
Wikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: François Fillon |