Francisca Ikhiede jẹ obinrin elere fóólibọọlu ti ilẹ Naigiria ti a bini 17, óṣu January ni ọdun 1996 si ilu Kaduna. Elere naa ti ṣere fun team Custom ilẹ Naigiria ati team awọn obinrin Naigiria ti National[1][2].

Francisca Ikhiede
Ọjọ́ìbí17 January 1996 (1996-01-17) (ọmọ ọdún 28)
Kaduna
Orílẹ̀-èdèNigeria
Iṣẹ́volleyball player

Aṣeyọri

àtúnṣe
  • Ni ọdun 2019, Francisca ati awọn akẹgbẹ rẹ kopa ninu Ere Idije Fóólibọọlu lagbaye to waye ni Yaoundé, Cameroon nibi ti wọn ti jawe olubori ti o si gba Gold medal[3].

Itọkasi

àtúnṣe
  1. https://en.volleyballworld.com/en/beachvolleyball/worldtour/2019/wwch2019/women/teams/945728-nnoruga-franco/francisca_ikhiede?id=142825
  2. https://women.volleybox.net/francisca-ikhiede-p27299/clubs
  3. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2023-03-18. Retrieved 2022-05-25.