Frank Lampard
Frank James Lampard je agba-oje agbaboolu-afesegba ti orile-ede United Kingdom. Oti figba kan je agbaboolu iko Chelsea ki won to wa yan-an laipe yii gege bi Akonimo-ongba fun iko Chelsea bakan naa lodun2019.[1] Gege bi agbaboolu, o je ogbontarigi agbaboolu aringbungbun ori papa lasiko re.[2] A bi Frank Lampard ni ogunjo osu kefa odun 1978.[3]
Awon Itokasi
àtúnṣe- ↑ "Manager profile". Transfermarkt. Retrieved 2019-09-19.
- ↑ S, Aditya M (2011-01-21). "World Football: The Top 10 Midfielders of the Past Decade". Bleacher Report. Retrieved 2019-09-19.
- ↑ "Manager profile". Transfermarkt. Retrieved 2019-09-19.