Freda Linde
Freda Linde (12 December 1915 – 7 March 2013[1] ) jẹ́ òǹkọ̀wé ìwé àwọn ọmọdé àti ògbufọ̀ ti ilẹ̀ South Africa. Èdè Afrikaans ló máa ń lò fún ìwé kíkọ rẹ̀. Ó ti ṣe ògbufọ̀ àwọn ìwé ọmọdé tó ju àádọ́jọ lọ sí èdè Afrikaans, French àti German.[2] Ó gba àmì-ẹ̀yẹ ti C.P. Hoogenhout Award ní ọdún 1964.
Freda Linde | |
---|---|
Ọjọ́ ìbí | Christovira Frederika Linde 12 December 1915 Swellendam, Western Cape, South Africa |
Ọjọ́ aláìsí | 7 March 2013 Cape Town, Western Cape, South Africa | (ọmọ ọdún 97)
Iṣẹ́ | Journalist, Writer and Translator |
Èdè | Afrikaans |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | South African |
Alma mater | Hoërskool Jan van Riebeeck |
Ayé rẹ̀
àtúnṣeÌlú Swellendam ni wọ́n bi sí, ó sì ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí i akọ̀ròyìn àti olóòtú títí wọ ọdún 1960. Láti ọdún 1960 wọ 1963, ó jẹ́ olóòtú ilé-iṣẹ́ atẹ̀wétà HAUM, àti láti ọdún 1964 wọ ọdún 1971 ó jẹ́ olóòtú tó ń ṣiṣẹ́ lórí àwon ìwé lítíréṣọ̀ ọmọdé ní John Malherbe publishers. Ó fẹ̀yìn tì láti ṣiṣẹ́ ìwé-kíko ní pẹrẹu ní ọdún 1972.[3]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Terblanche, Erica. "Freda Linde (1915 - 2013)" (in Afrikaans). Archived from the original on 10 July 2013. Retrieved 5 August 2013. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Freda Linde
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedStellenBosch2