Frederick Tluway Sumaye (ojoibi 1950) je Alakoso Agba orile-ede Tanzania tele lati 28 November 1995 titi di 30 December 2005.

Frederick Tluway Sumaye
Alakoso Agba ile Tanzania ekesan
In office
November 28, 1995 – 30 December 2005
ÀàrẹBenjamin Mkapa
AsíwájúCleopa David Msuya
Arọ́pòEdward Ngoyai Lowassa
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí1950 (1950)
Arusha, Tanzania
Ẹgbẹ́ olóṣèlúChama cha Mapinduzi