Funkaso, tàbí Pinkaso, jẹ́ oúnjẹ ilè Hausa[1] èyí tí wọ́n máa ń fi wheat díndín sè tí wọ́n sì máa fi ọbẹ̀, oyin tàbí ṣúga jẹ.[2] Oúnjẹ yìí jẹ́ nǹkan tí wọ́n fi ń ṣe ìpanu.

Funkaso
Alternative namesPinkaso
TypeDoughnut
CourseSide dish or snack
Place of originWest Africa
Main ingredientsflour, yeast, onion, scotch bonnet peppers, and salt
Àdàkọ:Wikibooks-inline 

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Funkaso | Traditional Snack From Nigeria | TasteAtlas". www.tasteatlas.com. Retrieved 2022-08-30. 
  2. "Funkaso Recipe by Rukky cooks". Cookpad (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-02-17. 

Ìjápọ̀ mìíràn

àtúnṣe