Funmi Jimoh
Oluwafunmilayo Kemi Jimoh (tí a bí ní ọjọ́ ọ̀kàn-dín-lọ́gbọ̀n oṣù karùn-ún, ọdún 1984, ní Seattle, Washington) [1] , tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Funmi Jimoh, jẹ́ olùfò gígùn (long jumper) ti Amẹ́ríkà, tí ó díje ní Òlímpíkì Ìgbà oòrùn ọdún 2008.
Òrọ̀ ẹni | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 29 Oṣù Kàrún 1984 Seattle, Washington |
Height | 1.73 metres (5 ft 8 in) |
Weight | 59 kilograms (130 lb) |
Sport | |
Orílẹ̀-èdè | Àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Amẹ́ríkà |
Achievements and titles | |
Personal best(s) | Long Jump 6.96 m (2009) |
Jimoh díje fún 'Rice University'. Ní Rice, Jimoh díje nínú méjéèjì fífò gígùn àti àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ 'sprinting', gẹ́gẹ́ bí àwọn òdiwọ̀n ọgọ́run mítà.[2]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣeWikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Funmi Jimoh |
- ↑ eurosport.com https://www.eurosport.com/athletics/funmi-jimoh_prs159237/person.shtml. Retrieved 2023-04-30. Missing or empty
|title=
(help) - ↑ "Q&A: Funmi Jimoh". Archived from the original on 2007-06-04. Retrieved 2023-04-30.
- USA Track & Field Profile
- NBC Olympics Bio[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- Funmi Jimoh's blog Archived 2008-09-20 at the Wayback Machine.
- Rice University profile Archived 2008-09-10 at the Wayback Machine.