Funmilayo Adebayo co ọ̀pọ̀ ènìyàn mọ̀ sí mmy GO[1] isjẹ́ ẹ̀váńjẹ́lísìtì Nàìjíríà tì Àríyànjiyàn pọ̀ lórí rẹ̀[2] àti Olùdásílẹ̀ Rapture Proclaimer Evangelical Church of God láti Ìpínlẹ̀ Èkìtì.[3][4][5] Wàásù rẹ̀ lóri bí òun ṣe lo ọdún 990 ní ìjọba Òkùnkùn lọ Káàkiri Nàìjíríà, àti wí pé èyí gbá ọkàn àwọn ènìyàn púpọ̀ mú.[4][3] Níbẹ̀, Ó sọ wí pé òun lo ọdún 990, [6][7] ní ìjọba òkùnkùn àti wí pé ó sọ ìrírí rẹ̀ àti òun tí ó mú òun lọ bá Kírísítì.[7]

Mummy GO
Ọjọ́ìbíFunmilayo Adebayo
Àsìṣe ìgbéọ̀rọ̀sílẹ̀: Àìdámọ̀ àmì ìdádúró-ọ̀rọ̀ sókí "{". 15 June 1967 (15 June 1967-{{{month}}}-{{{day}}}) (ọmọ ọdún Àsìṣe ìgbéọ̀rọ̀sílẹ̀: Àìdámọ̀ ọ̀rọ̀ "june".)
Ekiti State
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́Evangelist

Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Mummy G.O.: 'She used to be as lovely as her sermons but she changed'". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-01-15. Retrieved 2022-01-26. 
  2. "Exclusive interview wit Evangelist Olufunmilayo Adebayo - BBC News Pidgin". BBC News Pidgin. https://www.bbc.com/pidgin/tori-59926785.amp. 
  3. 3.0 3.1 Abiodun, Alao (January 9, 2022). "PROFILE: What you probably didn't know about ‘Mummy GO’ in viral memes". The Nation Newspaper (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved January 10, 2022.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. 4.0 4.1 Olajiga, Bimpe (January 10, 2022). "Reporter's diary: Inside Mummy GO's church in Lagos". The Punch (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved January 10, 2022.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. Olowolagba, Fikayo (January 9, 2022). "Mummy GO: Controversial messages of Funmilayo Adebayo who claimed to have seen Lucifer face-to-face". Daily Post (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved January 10, 2022.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. "Woman "Who Served Devil For 990 Years" Claims Football Is Demonic". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-09-24. Archived from the original on 2022-01-26. Retrieved 2022-01-26. 
  7. 7.0 7.1 "Mummy G.O: I spent 990 years in kingdom of darkness – The Nation Newspaper". thenationonlineng.net. Retrieved 2022-01-26.