Pápá ìgbafẹ́ ẹ Gani Fawehinmi, ti a mọ si Liberty Park, wa ni Ojota ní ẹ̀bá ọ̀nà Èkó sí Ìbàdàn àti Ìkòròdú, ní Ìpínlẹ̀ Èkó, ní Orílè-èdè Nàìjíríà. Wọ́n kọ́ ọjúta náà láti bu iyì fún ájàfẹ́tọ́ ènìyàn ní Nàìjíríà ti àún pè ní agbẹjọ́rò Gani Fawehinmi, won gbé ère Fewehinmi ńlá kan sí ààrin ọjuta náà. Ere yii ti o ga to ìwon-ẹse merinlelogoji ni ijoba ipinle Eko si ni April 21, Ọdun 2018 . Ọgba naa tun ni awọn atoka kekeke ti o so àwon itan kan nipa igbesi aye rẹ. Wón gbé awon ere miran ati awọn ijoko sibe láti mú kí ibè fani mon ra, kí o si ye fun itura àti isinmi. Ibe ni wón ti se ìwóde "Orile-ede Yoruba" ni 3 July odun 2021

Gani Fawehinmi Park, Ojota

Awon aworan

àtúnṣe

Awọn itọkasi

àtúnṣe