Gariep Dam
Ìdídò Gariep wà ní South Africa, nítòsí ìlú Norvalspont, ó ya agbègbè Ipinle Ọfẹ àti àwọn agbègbè Ìlà-oòrùn Cape . Ìwúlò àkọ́kọ́ rẹ̀ ni fún ìbomiwuko,ìlò ní ilé àti ilé-iṣẹ́ kódà fún iná-ọba.
Orúkọ
àtúnṣeÌdídò Gariep, lórí ìṣẹ̀dálẹ̀ rẹ̀ ńi ọdún 1971, ni a kọ́kọ́ ti ń pè é ní Ìdídò Hendrik Verwoerd lẹ́yìn Hendrik Verwoerd,tí ó jẹ́ ààrẹ ṣáájú àti lẹ́yìn ọjọ́ kọkànlélógún oṣù karùn-ún ọdún 1961, nígbàtí orílẹ̀-èdè náà yípadà láti Union of South Africa sí Orilẹ-ede South Africa . Síbẹ̀síbẹ̀, lẹ́yìn òpin ẹlẹ́yàmẹ̀yà, wọ́n wòye pé orúkọ Verwoerd kò yẹ. Lẹ́yìn ìfọwọ́sí,́ Orúkọ náà yípadà sí Gariep ni ọjọ 4 Oṣu Kẹwa Ọdun 1996. Gariep jẹ Khoekhoe fun "odò", orukọ atilẹba ti Odò Orange.[1]
Àwọn àwòrán
àtúnṣe-
Gariep Dam tó kún àkúnwọ́nsílè ní January, ọdún 2011
-
Àsìkò tí oòrùn wọ̀ ní Oviston Nature Reserve, ní apá Gúúsù odò náà.
-
Àmì ajúwèé-ọ̀nà tó kọrí sí odol náà.
-
Àwòrán odò náá
-
Forever Holiday Resort at Gariep Dam
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Dictionary of Southern African Place Names (Public Domain)". Human Science Research Council. p. 171.