Gaston Browne
Gaston Alfonso Browne (ọjọ́ìbí 9 Fẹ́ ebruary 1967) ni alákóso àgbà ilẹ̀ Antigua ati Barbuda. Òhun ni olórí orílẹ̀-èdè erékùṣù yìí láti ọdún 2014. Kó tó di olóṣèlú, ó jẹ́ oníṣẹ́ bánkì.
Gaston Browne | |
---|---|
Browne at the 7th Summit of the Americas | |
Alákóso Àgbà ilẹ̀ Ántígúà àti Bàrbúdà 4k | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 13 June 2014 | |
Monarch | Elizabeth II |
Governor General | Rodney Williams |
Asíwájú | Baldwin Spencer |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Gaston Alfonso Browne 9 Oṣù Kejì 1967 Villa/Point, Antigua and Barbuda |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Labour Party |
Alma mater | City Banking College University of Salamanca |
Net worth | US$11.1 million (2014)[1] |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ "Prime Minister Gaston Browne the $30 Million Man". 12 June 2016. Retrieved 7 November 2018.