Gbenga Agboola
Olugbenga Agboola OON (tí a bí ní ọdún 1985) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ó jẹ́ onímọ̀ ẹ̀rọ èdè Kọ̀mpútà àti oníṣirò ńlá. Òun ni olùdarí àti ọ̀gá ilé-iṣẹ́ Flutterwave.[1]
Olugbenga Agboola Àdàkọ:Post-nominals | |
---|---|
Fáìlì:Olugbenga Agboola.jpg | |
Ọjọ́ìbí | 1985 (ọmọ ọdún 38–39) Lagos, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Westminster, Massachusetts Institute of Technology |
Iṣẹ́ | Founder, Flutterwave |
Ìgbà iṣẹ́ | 2018–present |
Ipinle Eko ni a bí Agboolansí. Ó kàwé gboyè MBA ní ilé-ìwé MIT Sloan School of Management. Kí ó tó dá ilé-iṣẹ́ Flutterwave sílẹ̀ pẹ̀lú Iyinoluwa Agboyeji ní ọdún 2016, ó ṣiṣẹ́ bí i atuko ẹ̀rọ komputa ní ilé-iṣẹ́ PayPal, ó sì tún jẹ́ adarí ọjà títà ní ilé-iṣẹ́ Google.
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Adeoye, Sam (2022-04-16). "One good thing to expect from the Flutterwave and Gbenga Agboola ‘scandal’ - Nigeria and World News". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. Archived from the original on 2023-02-03. Retrieved 2023-02-03.