Gbénró Àjíbádé ni wọ́n bí ní ọjọ́ kẹjọ oṣù Kejìlá. Jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé,[1] olùgbéré-jáde, model àti olóòtú ètò.

Gbénró Ajíbádé
Ọjọ́ìbíGbénró Emmanuel Ajíbádé
December 8th
Maiduguri, Borno State, Nigeria
IbùgbéLagos, Lagos State
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Orúkọ mírànGbénró Emmanuel Ajíbádé
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́Actor, model, TV host film producer
Ìgbà iṣẹ́2008–present
Olólùfẹ́
Osas Ighodaro (m. 2015–2016)
Àwọn ọmọ1
WebsiteOfficial website

Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ àtúnṣe

Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Makurdi International School àti Mount Saint Gabriels Secondary School. Ó jáde ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì ti Benue State University nínú ẹ̀kọ́ Biology.[2]

Ó kópa gẹ́gẹ́ bí olú-èdá ìtàn nínú Soap Opera ti Tinsel tí ó aì tún ti kópa nínú eré a Gbomo Gbomo Express and The Wages.

Ajibade won Most Outstanding Actor/Model of the Year at the 2011 Nigerian Model Achievers Awards.

Personal life àtúnṣe

He was married to actress Osas Ighodaro, together, they have one daughter, Azariah Tiwatope Osarugue Ajibade. [3]


Àwọn fíìmù rẹ̀ àtúnṣe

Àwọn eré orí T.V àtúnṣe

See also àtúnṣe

Àwọn Ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. "Meet 19 Hottest Faces in Nollywood". TheNet.ng. Tayofik Bankole. Retrieved 28 July 2016. 
  2. "12 quick facts about Gbenro Ajibade". thenet.ng. Kayode Badmus. Retrieved 8 December 2015. 
  3. "Gbenro & Osas Ajibade name their baby girl - 'Azariah TiwaTope Osarugue'". Linda Ikeji. 2016-07-16. Retrieved 6 July 2016. 

Ìtàkùn ìjásóde àtúnṣe

Àdàkọ:Nigeria-actor-stub