Gbolahan Mudasiru
Olóṣèlú
Gbolahan Mudasiru(eni ti a bi ni 18 October 1945[1] ti o si fayesile ni 23 September 2003) jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó tẹ́lẹ̀.[2] O jé Gomina ipinle Èkó laarin Osu kinni odun 1984 si osù kejo odun 1986 nígba isejoba ologun Muhammadu Buhari àti Ibrahim Babangida.[3]
Gbolahan Mudasiru |
---|
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Africa Ìkọ kedereWho's who. 1991. ISBN 9780903274173. https://books.google.com/books?id=9EAOAQAAMAAJ&q=Gbolahan+Mudasiru+October+18,+1945.
- ↑ Afisunlu, Feyi (2013-05-28). "Former Lagos state First Lady, Foluke Mudashiru passes on". Daily Post Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-03-07.
- ↑ "Nigerian States". WorldStatesmen. Retrieved 2010-05-01.