Gelem, Gelem
Gelem, Gelem jẹ́ orin ìṣọ̀kan orílẹ̀-èdè Romani tí Žarko Jovanović ṣe àtinúdá rẹ̀. Ní ọdún 1971 ni wọ́n kọ́kọ́ ṣàmúlò orin yìí lẹ́yìn ogun àgbáyé kejì. [1]
Orin-ìyìn Ethnic | the Romani people |
---|---|
Bákanná bi | Opre Roma English: Up, Romanies |
Ọ̀rọ̀ orin | Žarko Jovanović, 1949 |
Orin | Žarko Jovanović, 1949 |
Lílò | 1971 |
Àwọn àkọ́lé orin náà
àtúnṣe- "Gyelem, Gyelem" (Hungarian orthography)
- "Jelem, Jelem"
- "Dzelem, Dzelem"
- "Dželem, Dželem" (alternative Croatian and Latin Serbian and Bosnian orthography)
- "Đelem, Đelem" (Croatian and Latin Serbian and Bosnian orthography)
- "Djelem, Djelem" (German and French orthography)
- "Ђелем, Ђелем" (Cyrillic Serbian and Bosnian orthography)
- "Ѓелем, Ѓелем" (Slavic Macedonian orthography)
- "Џелем, Џелем" (alternative Cyrillic Serbian and Bosnian orthography)
- "Джелем, джелем" (Russian, Ukrainian and Bulgarian orthography)
- "Opré Roma"
- "Romale Shavale"
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Romani Nationalism, Flag and Anthem". Archived from the original on 14 August 2012. Retrieved 13 November 2012.