Gelete Burka
Gelete Burka Bati ni a bini ọjọ kẹta leelogun, óṣu January, ọdun 1986 jẹ elere sisa lobinrin ilẹ Ethiopia to da lori ere sisa ti arin ati ọna jinjin. Abi Arabinrin naa si Kofele, Zone ti Arsi ni Oromia[1][2].
Òrọ̀ ẹni | |||||||||||||||||||||||||||||||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Ọjọ́ìbí | 23 Oṣù Kínní 1986 Kofele, Oromia Region | ||||||||||||||||||||||||||||||||||||
Height | 5 feet 3 inches (1.60 m) | ||||||||||||||||||||||||||||||||||||
Weight | 95 pounds (43 kg) | ||||||||||||||||||||||||||||||||||||
Sport | |||||||||||||||||||||||||||||||||||||
Orílẹ̀-èdè | Ethiopia | ||||||||||||||||||||||||||||||||||||
Erẹ́ìdárayá | Women's athletics | ||||||||||||||||||||||||||||||||||||
Iye ẹ̀ṣọ́
|
Àṣèyọri
àtúnṣeGelete kopa ninu idije agbaye ti IAAF ni ọdun 2006. Arabinrin naa gba ami ẹyẹ ti ọla lẹẹmẹta ninu idije agbaye ti inu ile[3]. Ni ọdun 2008, Gelete gba ami ẹyẹ ti ọla ti wura ni ere sisa ti metres ti 1500. Arabinrin naa kopa ninu idije agbaye lori ere sisa lati ọdun 2005 de 2011. Arabinrin naa ṣoju fun ilẹ Ethiopia ninu olympics ni ọdun 2008 ati 2012. Gelete gba ami ẹyẹ ti ọla ti idẹ ni ere gbogbo ilẹ Afirica[3]. Burka bẹrẹ ọdun 2013 pẹlu yi yege ni Cross Internacional Juan Muguerza. Gelete Burka gbe ipo kẹjọ ni wakati 30:26.66 ninu ere sisa ti summer olympics ti awọn óbinrin ti metres ẹgbẹrun mẹwa[4].