Genevive Clottey
Genevive Clottey jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ 25, óṣu April ni ọdun 1969. Agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi midfielder[1].
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 25 Oṣù Kẹrin 1969 | ||
Playing position | Midfielder | ||
National team‡ | |||
Ghana women's national football team | 6 | (0) | |
† Appearances (Goals). ‡ National team caps and goals correct as of 29 September 2003 |
Àṣeyọri
àtúnṣe- Genevive kopa ninu Cup FIFA awọn obinrin agbaye ti ọdun 2003[2].