Genfo

Àsáró ní ilẹ̀ Ethiopia àti Eritea

Genfo (gänəfo), Ga’at (ga'atə), tàbí Marca (Oromiffa: Marqaa) jẹ́ oúnjẹ alásèpọ̀ bí àsáró tí ó máa ń rí róbó tí ó sì máa ń ní ihò ní àárín rẹ̀ tí wọ́n máa bu ọbẹ̀ tí wọ́n fi butter, ata, sunflower, seed, nut, àti flax sí.[3]

Genfo/Ga'at
Genfo with berbere sauce.
TypePorridge (Volcano)
CourseTraditionally: Breakfast; or for Lunch and Dinner.
Place of originEthiopia,[1] Eritrea[2]
Region or stateAmhara, Tigray, Oromia, Eritrea
Serving temperatureHeated. Depending on region served in few remote areas with cool yogurt on the outside.
Main ingredientsBarley or wheat flour, water
Àdàkọ:Wikibooks-inline 

Genfo fara jọ oúnjẹ àwọn Arab kan tí wọ́n ń pè ní Asida. Wọ́n máa ń fi wheat tí wọ́n sè dáadáa, tí wọ́n sì fi igi pò ṣe Genfo. Tí wọ́n bá fẹ́ jẹ Genfo, wọ́n máa fi ihò ńlá sí àárín rẹ̀, tí wọ́n sì máa fi niter kibbeh àti berbere sí àárín rẹ̀.[4][5] Wọ́n lè fi ọwọ́ jẹ oúnjẹ yìí tàbí kí wọ́n fi ṣíbí jẹ ẹ́.[6]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe