Genzebe Dibaba
Genzebe Dibaba Keneni ni a bini ọjọ kẹjọ, óṣu February, ọdun 1991 jẹ elere sisa lóbinrin ilẹ Ethiopia to da lori arin ati ọna jinjin[1].
Genzebe Dibaba in 2016 | |
Òrọ̀ ẹni | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 8 Oṣù Kejì 1991 Chefe, Bekoji, Arsi Province, PDR Ethiopia |
Height | 168 cm |
Weight | 52 kg |
Sport | |
Orílẹ̀-èdè | Ethiopia |
Erẹ́ìdárayá | Women's Sport of athletics |
Event(s) | 1500 metres, 3000 metres, 5000 metres |
Team | NN Running Team (2023–) |
Coached by | Tolera Dinka |
Àṣèyọri
àtúnṣeNi ọdun 2008, Genzebe yege ninu idije agbaye U20 to si gba ami ẹyẹ ti ọla ti silver ninu mita ti ẹgbẹrun maarun[2]. Lati ọdun 2009 de 2017, Genzebe kopa ninu idije agbaye to si tun kopa ninu àṣèkagba awọn ere sisa naa. Ni ọdun 2010, Dibaba kopa ninu idije agbaye U20 lẹlẹkeji to si gba wura ni mita ti ẹgbẹrun maarun. Ni ọdun 2014, Dibaba ni a peni elerelobinrin ti Laureus fun ọdun naa[3]. Ni ọdun 2015, Dibaba jẹ elere sisa lobinrin ti IAAF agbaye ti ọdun naa[4]. Ni ọdun 2015, Genzebe kopa ninu idije agbaye ti mita ti ẹgbẹrun maarun to si gba ami ẹyẹ ti ọla ti idẹ ati wura ninu ayẹyẹ naa. Ni ọdun 2016, Genzebe kopa ninu Olympics ti Rio to si gba ami ẹyẹ ti ọla ti silver ni mita ti ẹgbẹrun kan ati aadọrun.