Georg Cantor
Georg Ferdinand Ludwig Philipp Cantor (pipe /ˈkʰæn-tɔ̝ː(ɚ)/ KANN-tor; German: /ɡ̥eˈɔʁk (ˈfɛʁdinant ˈluːtvɪç ˈfiːlɪp) ˈkʰantɔʁ/ (March 3 [O.S. February 19] 1845[1] – January 6, 1918) je onimo mathimatiiki ara Jemani to gbajumo gege bi oluda ero akojopo, to je ero ipilese ninu mathematiiki. Cantor sedasile pataki idojuko ikookan larin awon akojopo, o setumo awon akojopo alailopin ati awon akojopo agunrege, to si fihan pe awon nomba gidi "po lopolopo" ju awon nomba adaba lo. Looto, agbesiro Cantor so pe "ailopin awon ailopin" wa. O tumo awon nomba onikoko ati eleto ati isiro won. Ise Cantor se pataki nipa oye won, ohun gangan na si mo eyi.[2]
Georg Cantor | |
---|---|
Georg Cantor | |
Ìbí | Georg Ferdinand Ludwig Philipp Cantor Oṣù Kẹta 3, 1845 Saint Petersburg, Russia |
Aláìsí | January 6, 1918 Halle, Germany | (ọmọ ọdún 72)
Ibùgbé | Russia (1845–1856), Germany (1856–1918) |
Pápá | Mathematics |
Ilé-ẹ̀kọ́ | University of Halle |
Ibi ẹ̀kọ́ | ETH Zurich, University of Berlin |
Doctoral advisor | Ernst Kummer Karl Weierstrass |
Doctoral students | Alfred Barneck |
Ó gbajúmọ̀ fún | Set theory |
Religious stance | Lutheran |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |