Georg Simon Ohm (16 March 1789 – 6 July 1854) je asefisiksi ara Jemani. Gege bi oluko ni ile-eko agba, Ohm bere iwadi re pelu ahamo elektrokemika to sese je didawaye, ti ara Italia Oloye Alessandro Volta dawaye. Pelu awon irin-ise to da fun ra re, Ohm wadaju pe iseepin taara wa larin iyato alagbara (potential difference tabi voltage ni èdè Gẹ̀ẹ́sì) to je mimulo rekoja opa agbena kan ati iwo onitanna to waye. Ibasepo yi lamo loni si Ofin Ohm.

Georg Simon Ohm
Ìbí(1789-03-16)16 Oṣù Kẹta 1789
Erlangen, Germany
Aláìsí6 July 1854(1854-07-06) (ọmọ ọdún 65)
Munich, Germany
IbùgbéGermany
Ọmọ orílẹ̀-èdèGerman
PápáPhysics
Ilé-ẹ̀kọ́University of Munich
Ibi ẹ̀kọ́University of Erlangen
Doctoral advisorKarl Christian von Langsdorf
Ó gbajúmọ̀ fúnOhm's law
Ohm's phase law
Ohm's acoustic law
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síCopley Medal (1841)