George Akume
Olóṣèlú Nàìjíríà, Gomina ipinle Benue
George Akume (bíI Ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀ Oṣù kejìlá Ọdún 1953) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó jẹ́ Gómìnà Ìpínlẹ̀ Benue tẹ́lẹ̀. Òhun ni ààrẹ Ile-igbimo Asofin Naijiria tí ó sì jẹ́ aṣojú fún abasoju Àríwá-ìwòorùn Benue láti Ọjọ́ Ọ̀kàndínlọ́gbọ̀n Oṣù karún Ọdún 2007. [1] Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lẹ́yìn tí ó wọlé látàrí ètò ìdìbò ti oṣù kẹrin ọdún 2007 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú Action Congress of Nigeria.
George Akume | |
---|---|
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Benue | |
In office Ọjọ́ Ọ̀kàndínlọ́gbọ̀n Oṣù karún Ọdún 1999 – Ọjọ́ Ọ̀kàndínlọ́gbọ̀n Oṣù karún Ọdún 2007 | |
Asíwájú | Dominic Oneya |
Arọ́pò | Gabriel Suswam |
Ààrẹ Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣòfin Nàìjíríà | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga Ọjọ́ Ọ̀kàndínlọ́gbọ̀n Oṣù karún Ọdún 2007 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 27 Oṣù Kejìlá 1953 |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | All Progressives Congress (APC) |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Uja Emmanuel, Makurdi and Yusufu Aminu (2011-04-28). "Benue youths protest governorship poll result". The Nation. Retrieved 2011-05-02.