George Smoot
George Fitzgerald Smoot III (ojoibi February 20, 1945) je ara Amerika aseseedaonirawo, aseoroidaye, elebun Nobel, ati eni to gba ebun owo $1 million lori idije ori TV (Are You Smarter Than a 5th Grader?). O gba Ebun Nobel fun Isiseeda ni 2006 fun ise re lori COBE pelu John C. Mather tto fa iwon "ida ara dudu ati anisotropy ti Iranka iruonikekere agbaye."
George Smoot | |
---|---|
George Smoot at POVO conference in The Netherlands | |
Ìbí | George Fitzgerald Smoot III 20 Oṣù Kejì 1945 Yukon, Florida, U.S. |
Ibùgbé | France |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | American |
Pápá | Physics |
Ilé-ẹ̀kọ́ | UC Berkeley/LBNL/Université Paris Diderot-Paris 7 |
Ibi ẹ̀kọ́ | Massachusetts Institute of Technology |
Doctoral advisor | David H. Frisch[1] |
Ó gbajúmọ̀ fún | Cosmic microwave background radiation |
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí | Albert Einstein Medal (2003) Nobel Prize in Physics (2006) Oersted Medal (2009) |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Katherine Bourzac (12 January 2007). "Nobel Causes". Technology Review. Archived from the original on 2012-01-29. https://web.archive.org/web/20120129172243/http://www.technologyreview.com/article/17926/. Retrieved 2007-09-05. "And Smoot himself can still vividly recall playing a practical joke on his graduate thesis advisor, MIT physics professor David Frisch."