Georgia Oboh
Georgia Oboh jẹ elere golf lobinrin to jẹ Ọmọ British-Naigiria ti ó jẹ ọmọ ogun ọdun, arabinrin naa wa lati idile èlere golf nibi ti baba rẹ si jẹ ọkan ninu èlere golf naa ni central london. Arabinrin naa jẹ Akikanju Èlere golf larin awọn obinrin Afirica ti o si jẹ Naigiria akọkọ lati qualify fun tour Awọn ọdomọbinrin Europe nigba ti o wa ni ọmọ ọdun mẹtadinlogun[1].