Ghana Youth Environmental Movement

Ghana Youth Environmental Movement (GYEM), jẹ́ ẹgbẹ́ kan tí Gideon Commey àti àwọn ọ̀dọ́ kọ̀kan dá kalẹ̀ ni orílẹ̀ èdè Ghana ní ọdún 2012, ète ẹgbẹ́ náà ni láti ran àwọn ọ̀dọ́ lọ́wọ́ nínú jíjà fún títún àdúgbò ṣe.[1][2][3]

Ghana Youth Environmental Movement
Fáìlì:File:Ghana Youth Environmental Movement (Logo).jpg
Ìdásílẹ̀2012
IbùdóGhana

Láàrin ọdún 2018 sí 2019, GYEM dá Power Shift kalẹ̀, ìpàdé fún àwọn ọ̀dọ́ láti jíròrò lórí àwọn ǹkan ìdòtí ní àdúgbò àti bí wọ́n ṣe le tún àdúgbò ṣe. GYEM ṣe ìwóde lòdì sí àbá coal-fired power plants ní Ghana, wọ́n sì tún ṣe anti-coal campaign ní ọdún 2016.[4]

Àwọn ǹkan tí wọ́n ṣe

àtúnṣe

Ní oṣù Kẹ̀wá ọdún 2020, GYEM ṣe ilé omi tí wọ́n pe orúkọ rẹ̀ ní Kyensu Kiosk. Ète kíkọ́ ilé omi yìí ní láti pèsè omi mímu fún àwọn àdúgbò kọ̀kan ní ìletò Ga West Municipal. Àwọn àdúgbò yìí ní ìṣòro rírí omi mímu tó da mu.[5][6]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "GYEM announces advocacy coalition for ban of single-use plastics". Citinewsroom - Comprehensive News in Ghana (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-03-10. Retrieved 2022-06-21. 
  2. Darko, Daniel. "GYEM Urges Government to Protect Ghana's Forests from Destruction". www.gna.org.gh (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-06-21. Retrieved 2022-06-21. 
  3. "Akuvi Adjabs to head Sustainable Fashion Advocacy at GYEM - MyJoyOnline.com". www.myjoyonline.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-03-21. Retrieved 2022-06-21. 
  4. "GYEM announces advocacy coalition for ban of single-use plastics". Citinewsroom - Comprehensive News in Ghana (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-03-10. Retrieved 2022-06-21. 
  5. "Ghana Youth Environmental Movement commissions water project in Ga West". Citinewsroom - Comprehensive News in Ghana (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-11-05. Retrieved 2022-06-21. 
  6. "Ghana Youth Environmental Movement launches water project in low-income community in Accra". GhanaWeb (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-08-11. Retrieved 2022-06-21.