Gizdodo jẹ́ oúnjẹ̀ tí a fi iwe adìyẹ àti dòdò se. Ó jẹ́ oúnjẹ àfikún tí a máa ń jẹ ní ilé àti òde.[1][2]

Ìsọníṣókí

àtúnṣe

Àsepọ̀ yìí ni a sè nípa lílo dòdò, iwe adìyẹ, èròjà ìsebẹ̀ lóríṣiríṣi, àlùbọ́sà, tàtàṣé àti rodo. Wọ́n tún máa ń fi káròtù si.[3][4]

Dòdò àti iwe adìyẹ yẹn ni a máa kọ́kọ́ dín lọ́tọ̀ọ̀tọ̀, lẹ́yìn náà, a máa wá da méjèèjì pọ̀ sínu ata ọbè tí a sè pẹ̀lú àwọn èròjà tókù bíi àlùbọ́sà, ata, maggi, iyọ̀ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́è lọ. A lè jẹ gizdodo lásán, a sì lè je é pẹ̀lú ìrẹsì tàbí spaghetti.[5][6]

Àwọn ìtọ́ka sí

àtúnṣe
  1. "Gizdodo Recipe | Shoprite Nigeria". www.shoprite.com.ng. Archived from the original on 2016-10-20. Retrieved 2022-06-23. 
  2. "Eat Me: How To Make Gizdodo – The Whistler Newspaper". thewhistler.ng. Retrieved 2022-06-23. 
  3. "GL Recipe: Gizdodo and Zobo". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-06-11. Archived from the original on 2022-06-23. Retrieved 2022-06-23. 
  4. Onyeakagbu, Adaobi (2018-07-04). "Try this simple gizzard and dodo recipe". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-23. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  5. for #OunjeAladun, Omolabake (2020-10-01). "Plantain Gizzard Kebab". Ounje Aladun (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-23. 
  6. Lete, Nky Lily (2013-08-11). "Dodo Gizzard / Gizdodo Recipe (Gizzards and Plantains)". Nigerian Food TV (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-23.