Gladys Enti jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ afirica ti a bini ọjọ 21, óṣu April ni ọdun 1975. Agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi goalkeeper[1].

Gladys Enti
Personal information
Ọjọ́ ìbí21 Oṣù Kẹrin 1975 (1975-04-21) (ọmọ ọdún 49)
Playing positionGoalkeeper
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
Ghatel Ladies
National team
Ghana women's national football team19(0)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.

† Appearances (Goals).

‡ National team caps and goals correct as of 10 September 2007 (before the 2007 FIFA Women's World Cup)

Àseyọri

àtúnṣe
  • Gladys kopa ninu Cup FIFA awọn obinrin agbaye ti ọdun 2003[2].

Itọkasi

àtúnṣe
  1. https://www.eurosport.com/football/gladys-enti_prs414869/person.shtml
  2. https://www.playmakerstats.com/player.php?id=90485