Glafcos Clerides
Glafcos Clerides tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kẹrin ọdún 1919, tí ó sìn kú lọ́jọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù kọkànlá ọdún 2013 (24th April 1919-15th November 2013).[1] jẹ́ Ààrẹ orílẹ̀-èdè Kíprù tẹ́lẹ̀. Òun ni Ààrẹ karùn-ún orílẹ̀-èdè Cyprus, láti ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ́n oṣù kejì ọdún 1993 sí ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ́n oṣù kejì ọdún 2003 [2]
Glafcos Clerides | |
---|---|
4th President of Cyprus | |
In office 28 February 1993 – 28 February 2003 | |
Asíwájú | George Vasiliou |
Arọ́pò | Tassos Papadopoulos |
In office 23 July 1974 – 7 December 1974 | |
Asíwájú | Nikos Sampson (acting) |
Arọ́pò | Archbishop Makarios III |
1st President of the House of Representatives | |
In office 1960–1976 | |
Asíwájú | New office |
Arọ́pò | Tassos Papadopoulos |
1st President of DISY | |
In office 1976–1993 | |
Arọ́pò | Yiannakis Matsis |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Nicosia | 24 Oṣù Kẹrin 1919
Aláìsí | Nicosia | Oṣù Kọkànlá 15, 2013
Ọmọorílẹ̀-èdè | Greek Cypriot |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Democratic Rally (Demokratikos Synagermos) |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Eirini Kliridou (died 6 June 2007) |
Alma mater | King's College London |
Signature |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Glafcos Clerides: Man who steered Cyprus into EU dies
- ↑ "India-born former first lady of Cyprus passes away". On File. 2007-06-20. Retrieved 2020-01-22.